Apeere oro ise ninu gbolohun. Oro ise Ponbele :Eyo oro ise kan le da duro gege bi odidi gbolohun . Oro – Ise Asokunfa-: ni o maa n fa nnkan tabi to mu ki nnkan kan sele. ISE ASETILEWA Ewo lo kun ju lati gbe ero okan eni kale? (a) oro (b) awe gbolohun (d) odidi gbolohun. APOLA ISE (VERB PHRASE): Apola maa n je eyo oro tabi akopo awon eyo oro ti o le se ise oluwa ninu awe gbolohun ati odidi gbolohun. Eyi ni ki oro ise to bii meji tabi ju bee lo ninu gbolohun. Oro-oruko lo maa n jeyo leyin oro-atokun ninu gbolohun gege bi o sehan ninu awon oro ti a ko ninu awon gbolohun isale wonyi:- Olu fi ese ko Opa mi sere Mo ti oja de. Ose Karun-un: Ede- Awe Gbolohun Ede Yoruba. Oro-Atokun Oro-Atokun ni awon oro ti won n se ise atokun fun oro miiran ninu gbolohun. vii. apeere; Mo gba Oluwa gbo (Gbagbo) – mo gbagbo Jesu gba baba ABUDA TABI EYA ORO ISE. Ose Kefa: Ede- Oro Aponle Asa- Ojuse Apola ajemapon-on-le agbeyin ise: gege bi I oruko re , eyin oro ise ni o ti n jeyo ninu gbolohun lati fi kun itumo oro ise. ATUNYEWO GBOGBO ISORI GBOLOHUN Gbolohun le je eyo oro tabi akojopo oro ti o ni oro-ise ninu. Oga na Dele Ayomide fe Kunle Ode pa eran Baba gbin ogede Oro ise alaigbabo:Eyi ni oro ise ti ko ni oro oruko Abo gege bi Eni tabi ohun ti nkan Ose Keta: Ede- Apola ninu Gbolohun Ede Yoruba. O le je oro-ise ponbele, oro e. Oro - ise Oro - oruko Oro eyan. Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION ) EKA… Table of Contents Membership Required Related Posts : Nov 30, 2021 · The content is just an excerpt from the complete note from Yoruba Lesson Note from SS1 – SS3. Apeere orisi oro ise. 2. Apeere; Olu da? O maa n gba abo ninu gbolohun (oro miiran le jeyo leyin oro ise). apeere; Ole ko obe je Ologbo pa eku je Ige je ewa yo oro ise elela: Eyi ni awon oro onisilebu meji sugbon ti a le la sim meji lati fi oro miiran bo o ni aarin ti a sit un le lo won ti a ko ba fi oro miiran bo o ni aarin. Adebayo, F. d. apeere Bisi je iyan ni owuro Akanbi gun igi rekoja ewe Ogiri ile ti wo lule Apeere ; Aso ti a ri ni oja ko dara to Ile ti o n san fun wara ati fun oyin ni ile Naijiria Oro ise: Eyi ni koko fonran to n toke isele tabi nnkan ti oluwa se ninu gbolohun. Awon oro-atokun to wa ninu ede Yoruba nii – fi, ba, si, ni, fun ati pelu. litireso- Kika Iwe litireso. Apola Oro – ise (Verb phrase): Apola oro ise le je eyo oro tabi akojo po awon eye. Oro – Ise alapepada -: ni oro – ise ti a maa n se apetunpe re ninu gbólóhùn Apeere O ku o ku iwa re Ma da mi da bukaata mi. Gbolohun Olopo Oro-Ise: o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. O si maa ni oro asopo ninu pelu. ni a n lo lati fi kan gbolohun meji po. Eyi ni ohun ti oluwa se. Oro aropo afarajoruko: Eyin ni mo ri e. Asa- Ipa ti agbara Aje ko ninu Ise ati Iwosan; Ipagidina Iwosan ati Alaafia. Ose Keta: Ede: Aroko Awe gbolohun afarahe (subordinate clause): Inu ihun gbolohun olopo oro-ise tabi gbolohun onibo ni a ti maa n ri awe gbolohun afarahe. fun apeere. Apeere: jokoo Gbolohun ni a fi maa n se agbekale ero okan wa kale. Gbolohun gbodo bere pelu leta nla, ki o si pari pelu ami idanudoro. Asa Eto Eni si Ogun jije. Apeere: Kunle sare tete lo pon omi. - Edudelight. Oro ise alakanpo: A le pe oro ise yiii ni ‘Asinpo’. A le gbe won fun ra won bay ii ti won ko si ni so itumo gbolohun naa nu; Gbolohun alakanpo :- Gbolohun yii ni a maa n fi oro asopo so awon gbolohun miran po di eyo gbolohun kan. Gbolohun eleyo oro ise o maa n ni eyo oro ise kan. O se iku pa Yoruba lesson note for Secondary School – Edudelight. Gbolohun ni Ilana Ihun ni: gbolohun eleyo oro ise (abode), olopo oro ise (onibo) ati alakanpo. Apeere:Kunle tete lo pon omi wa. fun apeere, ‘Ola sun isu ta. Oro ise le je agbabo -- pakute mu ewure (ewure ni abo ) ,oluko na ola (ola ni abo ) , baba gbin ogede (ogede ni abo ) . Ti a ba yo oro ise: pon, ra, ro kuro ninu awon gbolohun oke wonyi, ko lee ni itumo. Asa wo lo maa suyo ninu dadakuada? (a) esin (b) eto oselu (d Dec 30, 2024 · (ii) Idowu lo si oja Oluwa oro ise apole atokun Gbolohun onibo/olopo oro –ise Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miran bo inu re. Ninu gbolohun olopo oro – ise. Bola lo Kunle jeun Mo je akara Kike mu omi Olorun wa Yoruba lesson note for JSS1 (Basic 7) – Edudelight. Apeere; Kin ni oro ise? Ise ilu lilu je ise atiran-de-iran. Apapo oro – oruko ati awe gbolohun. Ade sare gbe igi wa. Apeere O fi igi gba mi. apeere re; (i) Awon ole yoo sa bi awon ode ba fon fere Alaye:- (a) Awon ole yoo sa (b) Bi awon ode ba fon fere. Apeere: Ade je moinmoin Nike feran ese ii. Awon oro – ise asokunfa ni fi, da, se, mu, ko . Oro ise kikun /asodidi gbolohun – apeere wa , dake , dide , jokoo , sun , a ,o ti lo gbe ijokoo wa , ogede ti olu gbin Oro ise le je alaigbabo -- olu lo , sade wa . Gbolohun olopo oro ni gbolohun ti o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Takute mu Isola. Oro - asapejuwe. Ewo ni ki i se orisii gbolohun Yoruba (a) olopo oro ise (b) alakanpo (d) alatunto Awe gbolohun wo lo le da duro bi odidi gbolohun (a) olori (b) afarahe (d) asaponle. com YORUBA SCHEME OF WORK FOR SS ONE THIRD TERM ILANA ISE FUN SAA KETA FUN OLODUN KIN-IN-NI (SSONE) OSE KIN-IN -NI: EDE: ISORI ORO- ORO ORUKO ORIKI ORISI ORO ORUKO ISE TI ORO ORUKO N SE NINU NINU GBOLOHU ASA: ASA ISOMOLORUKO NI ILE YORUBA ORUKO AMUTORUNWA ORUKO ABISO MO ESIN TABI ISE,IDILE,ABIKU abbl ORIKI INAGIJE LITIRESO: ITUPALE EWI Oro-ise Asinpo : – ni oro-ise ti o maa n je meji tabi meta ninu gbolohun pelu oluwa kan. vi. Ose Kerin: Ede- Isori Gbolohun Olopo Oro-Ise. Apeere: Ade je moinmoin Nike feran ese Yoruba lessons for Secondary School. Mo wo o mo si ri. Bi apeere: -Dupe 'pon' omi. Eye fo si ori igi Jul 9, 2020 · Koko Ise: Ise oro Ise ninu gbolohun Oro Ise ni emi gbolohun. Sade 'ra' bata. com. Apola Oruko. Apeere oro-oruko ni ipo abo ni a fala si nidii yii: Oluwa ri Bisi Bade fe eba. Apapo oro oruko pelu eyan: Okunrin yen ni o mu Ewure merin ni won pa bo ifa Bola aburo Kemi ti wolu de Ounje die ni ki o se ȩ. Wayio, Oro ise ni oro ti o n fi isele inu gbolohun han TABI ki a so wi pe oro ise ni opomulero gbolohun. O da oorun mo mi loju. Oro-ise Asinpo : – ni oro-ise ti o maa n je meji tabi meta ninu gbolohun pelu oluwa kan. iye oro ise ti o wa ninu gbolohun yii ni iye gbolohun ti a le ri fayo. Ohun kan naa ni opomulero to n toka isele inu gbolohun. Adugbo wo ni orin etiyeri ti wopo ? (a) Ekiti (b) Oyo (d) Osun. Oro – ise ni o maa n je yo leyin oluwa. LETA KIKO, ASAYAN IWE TI IJOBA YAN, ISE ORO ISE NINU GBOLOHUN. Pataki orin lawujo Yoruba. Oro asopo bii, ati, sugbon, omo, tabi, abbl. Apapo oro – oruko ati awe gbolohun: Oro ti Kemi so dun won. Asa- Egbe Awo. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba Tuned gun igi osan “ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii: Abuda oro – ise i. Bi apeere : Sare Jade Jokoo Dide Sun Wa Sun Oro ise agbabo:: Eyi ni oro ise ti o gba oro oruko abo ninu gbolohun. Abo le jeyo ni aarin tabi ipari gbolohun. Oro ti o n so ohun ti oluwa se ninu awe gbolohun ati ninu odidi gbolohun o le je oro –ise ponbele, oro – ise agbabo ati asaaju oro – ise. Orimogunje, K. Olu n 'ro' amala ni ori ina. Feb 16, 2023 · Ko ise oro apejuwe ati oro aponle mejimeji pelu apeere; Ise Asetilewa: Yoruba akayege iwe Amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe kin-in-ni lati owo o L. Oro ti o Jul 14, 2022 · Ise asetilewa: Ko apeere meji lori orisii gbolhun ti o mo ITESIWAJU ISE LORI ISORI GBOLOHUN Gbolohun alaye: eyi ni gbolhun ti a n lo lati so bi n kan se ri. litireso- Kika Iwe Adakedajo. -Ola sun isu. ORO – ISE (VERB): Isori oro yii ni o maa n tola ohun ti oluwa se tabi toka isele ninu gbolohun. Gbolohun oke yii je gbolohun keji. Ara orisii gbolohun ni gbolohn olopo oro ise wa. Oro – ise ni opomulere gbolohun ede Yoruba, la i si oro-ise, irufe gbolohun bee yoo padanu itumo re. Okiki. Abo: ni olufaragba nnkan ti oluwa se ninu gbolohun . O maa n toka isele inu gbolohun laaarin oluwa ati abo (oro ise kikun). Ise Oro Ise:Oro Ise ni o maa n toka isele inu gbolohun. com SECOND TERM YORUBA LANGUAGE – JSS ONE ETO ISE FUN SAA KEJI Ose Kin-In-Ni: Atunyewo ise saa kin-in-ni Ose Keji: Ede: Orik ati eya gbolohun Ede Yoruba pelu apeere Asa: Oge sise ni ile Yoruba Litireso: Orin ibile to je mo asa igbeyawo, pipa ogo obinrin Mo,ise Agbe, ise ode. Ko iwulo ilu lilu meta pere ni ile ijosin. Bi apeere: Won ti jewo bi oro ti se ri gan-an Iwe meweaa ni Bolude ka Ojo naa fere wu oku ole Gbolohun iba tabi kani: eyi ni gbolohun ti a fi n so bi nkan se ri ati idi ti o fi ri bee. Oun ni on sise opomulero ninu ihun gbolohun ede Yoruba. Apeere: Oro ti Kemi so dun won Aso ti a ra ti gbo 2. Apola ajemapon-on-le yii pin si isori. Awon oro naa la fi sinu awon nisale yii Yoruba lesson note for JSS2 (Basic 8) – Edudelight. Check below for the appropriate link ISORI ORO Isori Oro ni, awon Isori to a le ba pade ninu Gbolohun. Apeere ; kunle ati olu lo si oja abike jeun sugbon ko yo abbl. Aye o fe ni fe oro. Gbolohun yii maa n ni oro ise bi meji, meta, merin tabi ju bee lo. Apeere: ade pa eku. Apeere oro ise ni: lo, sun, sare, jeun, se, wa, ri, han, ropo, duro, jokoo, rerin-in, dide, korin, sunkun, wo, pade, ro, ka, pade, to, to abbl. Gbolohun alakanpo: o maa n gbolohun meji ninu. Igbelewon :- Fun gbolohun ni oriki Irufe gbolohun wo ni wonyi ? Se o daa bee? Ade ra eja Aug 7, 2022 · OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. A maa nlo lati pase fun eniyan . com YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS TWO YORUBA JSS TWO ISE OOJO FUN SAA KIN-IN-NI Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni Atunyewo awon ewi alohun yoruba Eya gbolohun nipa ise won Asa igbeyawo ni ile Yoruba Kika iwe apileko ti ijoba yan Eya gbolohun Asa igbeyawo ni ile Yoruba (igbeyawo ode-oni) Kika OSE KINNI AKORI EKO: ORO – ISE Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. . 2xfxdf re5l k7z qpqg 6cw kstwrc vbgk mkzax aoom 01